Skip to content

Latest commit

 

History

History
129 lines (76 loc) · 6.48 KB

README.yor.md

File metadata and controls

129 lines (76 loc) · 6.48 KB

Open Source Love License: MIT Open Source Helpers

Akọkọ ilowosi

Lati dasi nko lakoko n'le, pataki ti a ba ronu nipa asise ti a le bapade, a fe ko rorun fun awon ilowosi akoko lati le dasi ise agbese lakoko, ise agbese yi a ko yin be ese le se, e tele ilana ni isalẹ

to ba le lo pipaṣẹ, awon ona mi re.

fork this repository

e fi git sori ẹrọ install it.

orita ibi ipamọ yii

orita ibi ipamọ yii, e te ' fork bọtini' ni oke oju iwe yi, e leyi a fun yin ni daako ni accounti yin

Dide ibi ipamọ

clone this repository

oya e de ibi ipamọ yi si account yin, e lo si githubu accounti yin, e te 'clone botini, ke wa te 'copy to clipboard' .

e sii ebute in ero ise yin, e te pipaṣẹ to be a labe oro yi si:

git clone "ọna asopọ ' te daakọ"

ibi, "ọna asopọ ' te daakọ" (lai awọn ' quote iṣmiṣ) lo je ono asopo ti e dide ibi ipamo (e dide ibi ipamo ise igbesi). e wo awon atono ti tele to n be loke

copy URL to clipboard

oye ko ri bi:

git clone https://github.com/oruko yin/first-contributions.git

ibi oruko yin ni oruko githubu accounti yin. ni bi yi en didako awon akoonu ' first-contributions repository in GitHubu' si ero ise yin.

ṣẹda ẹka

seda eka si ero, amo ko to sebe te pipaṣẹ yi si ibe

cd first-contributions

oya seda eka si pelu ' git checkout pipase:

git checkout -b <oruko to fe so eka to fe seda>

fun apere:

git checkout -b add-luke-oliff

(kon se dadun ki e lo "add", amo o daa fun irun nnkan bayii)

Ṣe awọn ayipada to ṣe pataki 'n ṣe awọn ayipada yẹn

oya shi faili Contributors.md ninu olootu ọrọ, fi oruko re mo awon oruko to 'n wan be, ma fe se akoko tabi igbeyn, fi si arin.

git status

to ba te pipase git status si ebute re, wa re awon ayipada ti ose

fi won mo eka ti ode pelu pipase yii git add:

git add Contributors.md

oya dawon papop pelu pipase yi git commit:

git commit -m "Add <oruko githubu account yin> to Contributors list"

yi <oruko githubu account yin> pada si oruko re.

Titari awọn ayipada si GitHub

te pipase yi git push:

git push origin <oruko eda ti e se>

yi <oruko eda ti e se> pada si orku e da ti ese ni ibere

Fi yer ayipada fer awotẹlẹ

Ti o ba lọ t' yer ibi ipamọ lori GitHub, iwọ yoo ri a Compare & pull request botini. te botini yen.

create a pull request

oya fi silẹ.

submit pull request

To ba ya a ma so gbogo yipada ti e se papo, e o gba iwifunni lori imeeli yin

Nibo ni lati lọ?

Ku ise oti pari boṣewa bisesenlo fork -> clone -> edit -> PR bisesenlo ti o ma bapade ni ise asowopo

Ṣe ayẹyẹ ilowosi yer 'ki o pin pẹlu' awọn ọkan ati awọn ọmọlẹyin nipasẹ lilọ’ si web app.

Ẹ lè darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ òṣìṣẹ́ wa tí kò já fáfá tí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ èyíkéyìí tàbí kí ẹ lè gba àlọ́ kankan. Darapo.

Bayi jẹ ki a bẹrẹ pẹlu' idasi' t' awọn iṣẹ akanṣe miiran. A ti ṣe akojọpọ awọn iṣẹ akanṣe pẹlu awọn ọran irọrun ti o le bẹrẹ. Ṣayẹwo awon re.

Tutorial lilo 'miiran Irinṣẹ

GitHub Desktop Visual Studio 2017 GitKraken VS Code Sourcetree App IntelliJ IDEA
GitHub Desktop Visual Studio 2017 GitKraken Visual Studio Code Atlassian Sourcetree IntelliJ IDEA